Orilẹ-ede Indonesia ti fi ofin de tita epo pupa lọ si awọn orilẹ-ede miran. Indonesia, to wa ni Gusu Asia, lo n pese ìpín to ju ilaji lọ ninu gbogbo epo pupa ti wọn n lo ni agbaye. Nkan to fa igbesẹ ...